Láti gba àlàyé míìràn nípa bí a ṣe lè lo Kickshaw, wínńdò ìtalólobó lè ṣí
sínú àtòjọ-ètò náà. A lè wọ ọ ní ọ̀nà méjì:

  - Nípa yíyan "Ìtalólobó" láti abala "Ìrànwọ́" ti mẹ́nù àtòjọ-ètò náà.
  - Nípa lílo àbùjá àtẹ bọ́tìnnì F1.

Àwọn ágúmẹ́ntì tí Kickshaw gbà:
